ASA Awe Lyrics
Awe Ibo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo
Anti to n gbe le I tosi
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo
O wi kpe o o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
O loyun fun o
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Anti ton loyun fun o
O to bi e l'omo/I wo iwo na
Anti to loyun fun o
O to bi e l'omo
O bi 'mo oh oh
O bi 'mo
Ire lo ni mu, ese
Irun ori, iwo dudu
Omo kpu pa ba wo lo se ri
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Ewa wo ja la fin
Oba ejigbo
Atabo, atako
Won ja la fin oba
La fin oba.
Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le, mabo loko
mabo l'eko
Mama to bi mama re
Ni mama mi
Emi na bi te mi
Moo ntomo lowo
F'omo l'oyon
Ma ko tire bami
Abo oro lan so f'omo
Luabi, to ba de nu re a do n di n di.
Din din
Hottest Lyrics with Videos
fda461d84cafe0fb6a7bff809409f1da
check amazon for Awe mp3 download these lyrics are submitted by musixmatch2 Songwriter(s) : Bukola Elemide, Cobhams Emmanuel Asuquo Record Label(s) : 2009 Downtown Music, LLC Official lyrics by
Rate Awe by Asa (current rating: 7.54)
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10
Meaning to "Awe" song lyrics