[Intro]
Dr. Dolo Entertainment (Yeah)
Ya ya ya ya
Spellz
Ṣʼongbọ
Emi Anita Baker, iwọ̀ ana shashanigga {Arnold Schwarzenegger}
Dimi lọwọ mu; ji'a jọ jojo Shina Peters
Iré ti de, I want to f*ck with higher nigga
Ọlọ'un gbọ! You are my only f*cking nigga
[Pre-Chorus]
Lori Lori standing (lori lori standing)
Fun mi lẹ̀yọkàn si (fun mi lẹ̀yọkàn si)
Ko lé rẹ̀ body, baby jo si (Ko lé rẹ̀ body my baby o)
Ara tin romi, baby fu'na si (Oh yeah)
Baby fi iná si (Oh yeah)
[Chorus]
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
(Ye!)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Tẹni
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Emi n'ṣé Ọlọmọgé loké loké loké(aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
[Bridge]
Ọlọmọgé askamaya
Allen avenue ni'le yin wa
Ọlọmọgé askamaya
Allen avenue ni'le yin wa
[Verse]
I'm the girl you shouldn't f*ck o
Chilling with the boys, you dey do 'dull it'
What?!
You tell me, are you done f*cking?
Emi nikan tàn, you shouldn't f*ck me!
Listen, I'm the girl you shouldn't f*ck o
Chilling with the boys, see no dulling
Mo jẹ lasan-lasan, mo tun turn 'di
Teni, mo fẹ knack, mo tun kọ'di
[Pre-Chorus]
Lori Lori standing (lori lori standing)
Fun mi lẹ̀yọkàn si (fun mi lẹ̀yọkàn si) (tee)
Ko lé rẹ̀ body, baby jo si (Ko lé rẹ̀ body my baby o)
Ara tin romi, baby fu'na si (Oh yeah)
Baby fi iná si (Oh yeah)
[Chorus]
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
(Ye!)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Tẹni
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Emi n'ṣé Ọlọmọgé loké loké loké(aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
[Bridge]
Ọlọmọgé askamaya
Allen avenue ni'le yin wa
Ọlọmọgé askamaya
Allen avenue ni'le yin wa
[Chorus]
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
(Ye!)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Tẹni
Ọmọgé loké loké (aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Emi n'ṣé Ọlọmọgé loké loké loké(aaah)
Ọmọgé loké loké (aaah)
Dr Dolor Entertainment
Spellz
Milla